Ipa ajakaye arun COVID-19 lori ona ati asa adayeba

Ìkéde enu ọna wa ni titipa ni owa ni ile ikawe gbangba ni Island Bay, Ilu Silandi titun latari ajakaye arun ati lati se adapada owo.

Ajakaye - arun erankorona odun2019-2020 ni ipa ojijji ati idaran lori awon ona ati eka asa adayeba. Idaamu ilera kariaye ati aidaniloju abajade lati odo ipa awon ajo bi eni kookan - ti a gba sise ati awon to daduro kaakiri eka naa. Awon eka ona ati asa adayeba n gbiyanju lati se agbateru gbangba ni igba gbogbo, ise lati pese aaye fun awujo si ohun asa adayeba; setoju aabo awon osise won, awon ikojopo ati awujo eda; nigbati o n fesi iyipada airotele ninu awose isowo pelu opin aimo.

Ni osu Keta ọdun 2020, opolopo awon ajo asa kaakiri agbaye ni o wa ni titipa laisi idaduro (tabi o kere ju pẹlu awọn iṣẹ wọn ti o dinku patapata), ati awon isafihan eniyan, awon isele, ati awon ise di fifagile tabi sun siwaju. Ni esi, awon akitiyan to lagbara tabi afikun ni won to seto nipase ise awon iru ero dijita, lati mojuto awon ise pataki pelu oro pooku, ati lati se akosile awon isele fun rarawon nipase awon ohun ini titun, pelu ise alatinuda titun latari ajakaye arun naa.

Opolopo awon eniyan kaakiri ajo yii ni yoo padanu awon ise agbase won fun igba die tabi titilai tabi ise won pelu orisisi iwon ikilo ati iranlowo owo to wa. Bakanna, igbiyanju owo lati odo ijoba ati awon alaanu fun awon osere yoo pese iyato gidigidi ati awon ipele ti o da lori eka ati orile ede naa. Gbogbo eniyan ni o beere fun ise asa lati pada, sugbon ni akoko aimo ati pelu ero pe oririsi iriri ni yoo gbajumo.


© MMXXIII Rich X Search. We shall prevail. All rights reserved. Rich X Search